Zlatan – Bust Down Lyrics

Bust Down Lyrics (feat. Asake)

Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o

Cash money ọmọ iya mi jọ
Jẹun soke ọmọ no dey dull
Calli kush yeruku we dey puff
Puff puff pass my G ma jẹ k’ọn mọ
Sometimes me I pray to the Lord
Let thy will be done in my life o dẹ jọ
Many, many things I no fit talk money fit me I don’t wanna be poor
Ọmọ iya mi ṣaanu mi
Wọn o ni ko ba ẹ, o ni ni injury
E dey gba for my body like skuri
Lagbaja sọ pe ko ni pẹ su mi
Sentimamọkan Sabu’, Saburi
Ngba tẹ joju mi ṣe mo wa ku ni?
Mi o le ja boxing mi o n ṣe Tyson, o baby no fight me

Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o
Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o

Kuro bẹ, ah
Ọmọ ologo daya
Awọn ọlọtẹ gara mi o kana
If e no be Messiah bawo ni mo ṣe ma gbe half a million dollar saya?
Mi o gara mi kana nnkan toju mi ri toju ẹ ba ri o le mayan
If e no be money hapụ m aka
O fẹ gbemi mọra ẹ ma wo barawo bansa

Iru blessing yii ko n ṣe fun ọmọ ọlẹ
Poverty ba mi po, mo yogo sẹ mo yọbẹ
Ṣe l’ọn buga tẹlẹ nisin o n tọrọ ọkẹ
Once beaten twice shy ọlọgbọn l’ọlọdẹ
Say! If riches na drug I go take overdose
Kowo yẹn jaburata ki n ma rogun loan
Palmpay agents no near my zone
Na credit alerts I wan dey see for my phone

Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o
Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o

Mo ni why tẹ n fọ pe life mi pada be like this?
Malu ti o niru Oluwa lo n ba leṣin
Ọmọ were Oluwa lo n ṣọ
A gbegba orin, wọn ni ki la fẹ kọ?
Mo ni pe ehn ehn, loju ọta mi mo pada di celeb (Ki lo wi?)
Awọn were wọn ni mo lọ Cele (Ki lo sọ?)
Iku pa diet mo ti yọ ẹkẹ, gbọmọ wọnu Paris ka lọ jaye Schengen
Emi laye mi Ọlọba mi o le sẹmpẹ o (Sẹmpẹ)
Ninu Masseile mo ma jẹ n’bẹ
Kẹlẹgbẹ ko ma mẹgbẹ o
Kọrọ ẹrin ma pada dọrọ lẹbẹ o
Them say industry na yeba yebo
Mo kọti ikun si wọn mumsy ni pe ki n carry go
Fun wọn ni gbẹdu to dun, gbẹdu to dun bi edikayikong ati ẹba Ibo

Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o
Adura agba o
Owo yẹn a wa o
Bust down, bizza bizza la wa o
Ọmọ ologo daya o

Focus, focus! Mo n focus always on my grind mo dẹ n gbadura
Ko dun ko pọ, aniṣẹku la ma ma ni lọla Satira’
I no fit talk I no get stamina
My swag is for foreigner
I wan my capital
Mo sare wọ Burj Khalifa
Mo dẹ n pawo now
Next stop o di Yankee now