Tope Alabi – Loro Lero Ati Ni’se Lyrics

Tope Alabi Hymnal (Volume 1)

Tope Alabi – Hymnal (Volume 1)

Tope Alabi Loro Lero Ati Ni’se Lyrics

[Verse 1]
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

[Verse 2]
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

[Verse 3]
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Written by; Tope Alabi
Released date; 9 November, 2020

Loro Lero Ati Ni’se Lyrics by Tope Alabi

    Credits & Song Knowledge

  • Song Title:
  • Performed by:
  • Written by:
  • Genre:
  • Album:
  • Release Date: