Reekado Banks, Seyi Vibez & Del B – Fakosi Lyrics

Fakosi Lyrics

Durọ mọ mi ọmọ durọ mọ mi tonight
Jẹ ka do something tonight
Something tonight

Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi , o wọ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito

Wọn ranju wọn ranju
Nibo lo ti wa, nibo lo ti wa?
Wọn a gbele ma gbọ, wọn a gbele ma gba
Guarantee guarantee
Beautiful, lo tun ṣana (Mmm mmm)
Bad belle enemies, won’t let me drink water drop cup eh
Wọn tun ti n sọrọ mi
Put it inside your tea make you drink am o
Captivating captivating
Mo gbe, bad girl, ọmọ did not come to play
She no come to play
Uhn awọn lo n ṣere

Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi , o wọ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito

Guaranteed guarantee
Ikorodu touchdown Yankee
Baby talk to me nicely
Mo kọ pop, kọ fuji
Competi’ competi’
Do I look like I am 30?
Ade ori ọkin
Wọn gbele ma gbọ, wọn a gbele ma gba
(Iyọnu Ọlọrun) Everyday
(Iyọnu Ọlọrun) Anyway
(Iyọnu Ọlọrun) Dance to my disco

Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito

Boya ka fagbo bi Fela
Awọn kan fa cigar
Wọn n jo wọn n bend down
Ẹla oju kan ẹla
Wọn ni mi fagbo bi Fela
Awọn kan fa cigar
Wọn n jo wọn ẹla
Ẹla oju kan ẹla oh

Areeky baby o
Oluwaloseyi
Fagbo bi Fela
Tun fa cigar
O ya ka fagbo bi Fela
Awọn kan fa cigar
Wọn n jo wọn n bend down
Ẹla oju kan ẹla